Mojúbà Olódúmarè Mojúbà Olódúmarè Mojúbà Baba mi Olódúmarè Mojúbà Baba mi Olòrun Mojúbà Baba mi Olódúmarè Mojúbà Baba mi Olòfin Mojúbà Àkódá Mojúbà Asèdá Mojúbà Ilè-Ògéré Mojúbà Ilè-Àiyé Mojúbà Ìlà-òrùn Mojúbà Ìwò-òrùn Mojúbà Àrìwà Mojúbà Gúúsù Mojúbà Ajaí-odún Mojúbà Oní-odún Mojúbà Odún-olá Mojúbà Baba Mojúbà Yeye